Ààrẹ

Song

Ààrẹ

Brymo · 9: Èsan · 2021 · 1:58

Lyrics

Eré òkúta àti gíláàsì Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré Eré òkúta àti gíláàsì Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò Ọlọ'ọ'pá wá o, ó máa gba rìbá Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré Eré òkúta àti gíláàsì Mo ṣáná si, ó máa ta pàò pàò Ọlọ'ọ'pá wá o Ẹku owurọ o Ìròyìn láti ìgboro la mú wá kàn yín létí Wọ'n ní ní òwúrọ' yìí, àwọn ọmọ éèès! Wọ'n ti jà wọ"gboro Wọ'n dẹ' ti ń dáná sunlé Wọ'n ti ń dáná sun oko Àt'ọkọ' ayọ'kẹ'lẹ' àti èyí tí ò yọ'kẹ'lẹ' Gbogbo ẹ' ná ń dáná sun Ẹ gbélé yín o Ẹ ṣọ'ra yín o Ẹ pe àwọn ọmọ yín sọ'dọ' Èyí tí ò bá lọ sílé ìwé, kó jókòó Kí Ọlọ'run kí ó máa ṣọ' gbogbo wa o Láyọ' o, ẹ ṣé Ààrẹ ń bọ' l'ájò Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi Orí mi ló gbé mi k'ore Ààrẹ ń bọ' l'ájò Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú Èmi bàbá ọba, mo dúró ṣigidi Orí mi ló gbé mi k'ore

Lyrics provided by LRCLIB.

Popular by Brymo