Intro (Live)

Song

Intro (Live)

Aṣa · Asa Live in Lagos (Live) · 2017 · 6:27

Lyrics

Awe! Ibo lo lo ka Ta fi n wao ka Ibi o ba lo je a mo Anti, to n gbe le itosi O wa o wa le yi Ati o jo meta atabo O wi kpe o o O loyun fun o Oyun oshu meji O loyun fun o Ani wipe oo O loyun fun o Iwo Iwo naa O loyun fun o Wahidi omo sekina Omo muyina Omo mohammed Wahidi omo sekina Omo muyina Omo mohammed Anti ton loyun fun o O to bi e l'omo Iwo iwo na Anti to loyun fun o And O to bi e l'omo Iwo Iwo naa O bi 'mo oh oh O bi 'mo O bi 'mo oh oh Omo so layo Ire lo ni mu, ese, Irun ori ire dudu omo pu pa ba wo lo se ri Wahidi.omo sekina Omo muyina Omo mohammed Wahidi.omo sekina Omo muyina Omo mohammed Ewa wo ja la fin Oba ejigbo Ha Atabo, atako Won ja la fin oba La fin oba. Haaa Wahidi omo muyina ni Omo sekina O foju mi ri mabo Mabo ni le, mabo loko mabo l'eko Abo oro lan so f'omo Luabi, to ba de nu re a do n di n di. Din din

Lyrics provided by LRCLIB.

Popular by Aṣa