
Lyrics
E-le-le-le-le-le-le, ẹyín awo lárí
Le-le-le-le-le-le, ẹyín awo lárí
Gbogbo ti ẹ ṣe fún wá
Àwọn to fẹ wá o dún mo wọn
Àwa o bínú ẹnìkan
B'ènìyàn bínú ẹnìkan o mọ
Ọjà Oyìngbo, kò mọpe ẹnìkan ó wá o
B'ọkọ kàn o re'jìnrìn, ẹgbẹ-gbẹ'rún rẹ à lọ
Ṣugbọn b'aba ṣẹ wọn o
Agbàgbà, wọn a forí jí wa o, awo
Ṣùgbọ'n, t'ábà ṣẹ wọn o
Agbàgbà wọn a forí jí wa o, awo
Wọn a forí jí wá o, àgbàgbà, wọn a forí jí wa o, awo
E-le-le-le-le-le-le, ẹyín awo lárí
E-le-le-le-le-le-le, ẹyín awo lárí
Gbogbo ti ẹ ṣe fún wá
Àwọn to fẹ wá o dún mo wọn
Àwa o bínú ẹnìkan
B'ènìyàn bínú ẹnìkan o mọ
Ọjà Oyìngbo, kò mọpe ẹnìkan ó wá o
B'ọkọ kàn o re'jìnrìn, ẹgbẹ-gbẹ'rún rẹ à lọ
Ṣugbọn t'aba ṣẹ wọn o
Agbàgbà, wọn a forí jí wa o, awo
Wọn a forí jí wa o, àgbàgbà, wọn a forí jí wa o, awo
Wọn a forí jí wa o, àgbàgbà, wọn a forí jí wa o, awo
Lyrics provided by LRCLIB.
Popular by Fela Kuti
#TitleAlbum








