Ogbo

Song

Ogbo

Lyrics

Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Ọmọ Dafidi, léni ti o ba djè Oba Itẹ rẹ o monlè kpélou wura Oti wa ni shọ lowo Kiniun méji Kiniun meji ti ko jéra o N'tori agbara won foun yin l'okan bale Kiniun meji ti ko jéra o Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Shugbọn ma gbagbé l'ayé, kpé ojo buruku kan owa Igbati won ji janu oruka rè Ànjọnú Sakhar lo fọ agbara rè Ànjọnú Sakhar lo dji oro rè Awon éyé ijosin Awon éjé korira Awon éyé ijosin Awon éjé korira Asho ti awon olowo Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oh, Oh, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Ọmọ Dafidi, léni ti o ba djè Oba Tabili rè nin smaragdu On simi lori ẹssẹ oniyèbiyè mẹrin Kiniun meji ti ko jéra o To fun yin ni agbara, okanbalé Kiniun meji ti ko jéra o Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Shugbọn ma gbagbé l'ayé, kpé ojo buruku kan owa Igbati won ji janu oruka rè Ànjọnú Sakhar da yin kpada bi talaka Ànjọnú Sakhar da yin kpada bi alagbé Awon éyé ijosin Awon éjé korira Awon éyé ijosin Awon éjé korira Asho ti awon olowo Kpelou asho ti awon talaka mawo lo si boji Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh, Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Igi ọgbọ Oba, Oh, Oh, Oh, Oh Oba awon Oba, Oba awon Oba, Oba awon Oba Oh

Lyrics provided by LRCLIB.

Popular by Ibrahim Maalouf