GTA

Song

GTA

Seyi Vibez · SWAGUU · 2026 · 2:35

Lyrics

Tell the woman 'o ma jere iṣẹ rẹ' Akaba to dẹ l'awa fi gbera I don go many places I don see many faces Real life GTA Mo da bi grand theft auto Gamer! I don go many places I don see many faces Real life GTA Mo da bi grand theft auto Automatically, baby Automatically, baby Mo maa jẹ'ṣẹ yẹn Toyin Tomato Uhn-uhn Baby mọ pe aye pọ gan-an I can never joke with this your love Carry me go, carry me comot Anything you want, ba mi sọrọ Uhn-uhn-uhn, no suffocation I dey go jẹjẹ o, ọmọ Eko Carry me for yansh, sisi Debo Oh, Fujiana Mo ya'wo kọrin ki n to ṣe aṣela Right now, Ẹmi-Mimọ bale mi All white dressed, and I wan party Awọn ọmọ oro n cho, wọn wọ Frank Muller Mo ta tan sibẹ ki n le gba mulla Lat'ọmọde mo ti jọba Lat'ọmọde mo ti jọba, ah Fujiana, ko ṣe normal I don go many places I don see many faces Real life GTA Mo da bi grand theft auto Gamer! I don go many places I don see many faces Real life GTA Mo da bi grand theft auto Automatically, baby Automatically, baby Mo maa jẹṣẹ yẹn Toyin Tomato Tell the woman 'o ma jere iṣẹ rẹ' Akaba to dẹ l'awa fi gbera Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ Ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa Ẹ ran mi niṣẹ, mo dẹ n jẹ ẹ Akaba to dẹ l'awa fi gbera Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ Ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa Tell the woman 'o ma jere iṣẹ rẹ' Akaba to dẹ l'awa fi gbera (akaba to dẹ l'awa fi gbera) Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ (Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ) Ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa (ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa) Ẹ ran mi niṣẹ, mo dẹ n jẹ ẹ (ẹ ran mi niṣẹ, mo dẹ n jẹ ẹ) Akaba to dẹ l'awa fi gbera (akaba to dẹ l'awa fi gbera) Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ (Baba lo maa mọ bo ṣe jẹ-ẹ) Ilahi la n pe, o dẹ ma gbe e wa

Lyrics provided by LRCLIB.

Popular by Seyi Vibez